Baba mimo lyrics by Toba Peters
Baba mimo lyrics
Chorus
Baba mimo modupe lowo re
Baba mimo
modupe lowo re
Bemi ba legberun ahon koto yin Oluwa
bi mo rofo bi mo teba bi mo gun Yan
Oluwa oni je e
Ope mo mu wa o
Baba mimo
Ope mo mu wa oo
Baba gbo oe mi
Verse 1
Loju ewure bi kalapata o lo s'orun
Koma la so ko maa was ki sa oo
K'omo eleran ko maa jegun
Iwo la lati leyinmi Apata to mo gbo Jule
Mo wa d'agbado Inu igo
Awo moju f'ediye
Ooo ojo loro ti Ile tifimu
From January to December ooo isele lonsele
Eni see ni lore lan duoe fun o, mo mope was,
Eni see ni lore landupe fun o
Mo wa dupe
Refrain
Eni Ase lo re, ti lo dupe oo,
bi olosa, ko ni leru lo ni
Aja ki gbagbe olore re
Mowa duoe o baba
Aja ki gbagbe olore re
Mo mope was o, baba
Chorus
Baba mimo modupe lowo re
Baba mimo
modupe lowo re
Bemi ba legberun ahon koto yin Oluwa
bi mo rofo bi mo teba bi mo gun Yan
Oluwa oni je e
Ope mo mu wa o
Baba mimo
Ope mo mu wa oo
Baba gbo oe mi
Verse 2
Ise se mo logun odun
Iya ba jomo logbon OSU moso,
tibo ba Pomo apada leyin Omo baba modupe
Ore to se fun mi lo mumi wayo lodo re oo
Iranlowo alaini oo baba mi
Agbani lagbatan moso
Tayelolu mo yo oo
Olruntoba nduoe oni kin ma yin oo
Agunle chemba one
I celebrate your name
Onyeoma, daddy, ooooo
Onyeoma.
Refrain
Eni Ase lo re, ti lo dupe oo,
bi olosa, ko ni leru lo ni
Aja ki gbagbe olore re
Mowa duoe o baba
Aja ki gbagbe olore re
Mo mope wa o, baba
Chorus
Baba mimo modupe lowo re
Baba mimo
modupe lowo re
Bemi ba legberun ahon koto yin Oluwa
bi mo rofo bi mo teba bi mo gun Yan
Oluwa oni je e
Ope mo mu wa o
Baba mimo
Ope mo mu wa oo
Baba gbo oe mi
Call: Egbe baba ga eba mi gbe ga oo
Res: Egbe baba ga, eledunmare akiri sore
Call: Olope lope ye baba, iyin ye oo Egbe ga
Res: Egbe baba ga, eledunmare akiri sore.
Call: Okunrin eba mi gbe ga, obinrin Egbe Jesu ga
Res: Egbe baba ga, eledunmare akiri sore
Call: Eni to dawa SI do Jo oni ye, iyin ye o baba
Res: Egbe baba ga, eledunmare akiri sore
Call; Omode Agba egbega, gbogbo ijo lapapo egbega
Res: Egbe baba ga, eledunmare akiri sore
Call: Iranlowo kan ti mo mo alati leyin mini oo
Res: Egbe baba ga, eledunmare akiri sore
Call: Gbogbo christians agbaye ebami gbe Jesu ga
Res: Egbe baba ga, eledunmare akiri sore
Comments
Post a Comment