Baba mimo lyrics Chorus Baba mimo modupe lowo re Baba mimo modupe lowo re Bemi ba legberun ahon koto yin Oluwa bi mo rofo bi mo teba bi mo gun Yan Oluwa oni je e Ope mo mu wa o Baba mimo Ope mo mu wa oo Baba gbo oe mi Verse 1 Loju ewure bi kalapata o lo s'orun Koma la so ko maa was ki sa oo K'omo eleran ko maa jegun Iwo la lati leyinmi Apata to mo gbo Jule Mo wa d'agbado Inu igo Awo moju f'ediye Ooo ojo loro ti Ile tifimu From January to December ooo isele lonsele Eni see ni lore lan duoe fun o, mo mope was, Eni see ni lore landupe fun o Mo wa dupe Refrain Eni Ase lo re, ti lo dupe oo, bi olosa, ko ni leru lo ni Aja ki gbagbe olore re Mowa duoe o baba Aja ki gbagbe olore re Mo mope was o, baba Chorus Baba mimo modupe lowo re Baba mimo modupe lowo re Bemi ba legberun ahon koto yin Oluwa bi mo rofo bi mo teba bi mo gun Yan Oluwa oni je e Ope mo mu wa o Baba mimo Ope mo mu wa oo Baba gbo oe mi Verse 2 Ise se mo logun odun Iya ba jomo logbon OSU moso, tibo ba P...
Comments
Post a Comment